-
Ijoba Apapo, Ti So Pe, Aheso Oro Lasan Ni Pe Aarun Romolapo-Romolese Bee Sile
Ijoba apapo ti so pe ko si ooto ninu iroyin to n ja rohinrohin pe aarun romolapa romolese ti be sile lawon ipinle kookan. Ijoba fowo idaniloju re soya pe ko ti si isele aarun naa tuntun nile yi lati odun 2016. Ogaagba eto idagbasoke ilera alabode, Dokita Faisal Shuaib eni to ni ko si…