-
Ajo NCC Fokan Awon Eniyan Bale Lori Oju Opo Ibaraenisoro Won
Ajo to n risi oto ibanisoropo nile ye NCC, ti ni ko si ifoya pe won yio di opo numba ibanisoro awon eniyan nitori igbese siso numba won mo ti idanimo omo ile yi to nlo lowo. Alukoro ajo NCC, omowe Ikechukwu Adinde ninu atejade to fi sita ni ko si idi Kankan lati foya…