Ajo to n risi oto ibanisoropo nile ye NCC, ti ni ko si ifoya  pe won yio di opo numba ibanisoro awon eniyan nitori igbese siso numba won mo ti idanimo omo ile yi to nlo lowo.

Alukoro ajo NCC, omowe Ikechukwu Adinde ninu atejade to fi sita ni ko si idi Kankan lati foya nitori igbese naa je lati daabobo awon eniyan ni.

Ajo NCC lo ti ndahun si oniruru iroyin to ti nko ipaya baa won eniyan lori sise numba ibara enisoro won mo ti idanimo omo ile yi won ti won ni o lee yori si didi oju opo ibaraenisoro won.

O ni igbese naa je lati seranwo fun eto  aato gbogbo, aba isuna ati waon eto amayederun.

Net/Dada

pub-5160901092443552

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *