Home Posts tagged àjọ SUBEB
Yoruba

Alága àjọ SUBEB fi gbèdéke síta fún píparí isẹ́ àkànse àwọn ilé-ìwé girama

Alága ìgbìmọ̀ tón rísí ètò ẹ̀kọ́ káríayé nípinlẹ̀ Èkìtì, ọ̀jọ̀gbọ́n Fẹmi Kinwumi ti fi gbèdéke ìparí osù yíì lélẹ̀ fáwọn agbasẹ́ se tó wà nídi isẹ́ àkànse àwọn ilé-ìwé girama mẹ́rin tíjọba sẹ̀sẹ̀ dá sílẹ̀, láti fi parí isẹ́ àkànse ọ̀hún. Ìlú Adó-Èkìtì ló ti kéde gbèdéke ọhun lákokò ìpàdé kan tó Continue Reading