Alakoso keji feto idaleese sile, eto okoowo ati oro aje lorileede yi Ambassador, Marian Katagum ti tenumo igbiyanju isejoba Aare Buhari lori atileyin sise fawon akanda eda lorileede yi. Arabinrin Katagum siso loju oro yi lasiko to n gbalejo asoju egbe awon obinrin to je akanda eda, eyiti akowe Continue Reading