Home Posts tagged àrùn covid tuntun
Yoruba

Ìpínlẹ̀ Èkó ti gbé àwọn orílẹ̀ èdè mẹ́rìnlá sábẹ́ àmójútó láti dènà ìtànkálẹ̀ ẹ̀yà àrùn covid tuntun

Gẹ́gẹ́bí ara ọ̀nà láti dènà kí àrùn covid 19 tuntun bẹ́ sílẹ̀, ìjọba ìpínlẹ̀ Èkó ti fi àwọn orílẹ̀ èdè mẹ́rìnlá kan sábẹ́ àmójútó tó péye. Alákoso fétò ìlera nípinlẹ̀ Èkó, ọ̀jọ̀gbọ́n Akin Abayọmi, ló sọ̀rọ̀ yí lásìkò tón bá àwọn akọ̀ròyìn sọ̀rọ̀, óní ìgbésẹ̀ yi ló se pàtàkì lẹ́yìn tí wọ́n Continue Reading