Aare Muhammadu Buhari ti soodi mimo fun awon Gomina meje to wa lapa ariwa iwooorun orileede yip e ki won tete lo wa ona ti opin yio fi ba ose tawon agbebon nse lagbegbe naa. Gomina ipinle Kebbi, Atiku Bagudu lo foju oro yi lede lasiko ipade awon ti oro Alafia eti aabo, ati isokan […]Continue Reading