News Yoruba

Aare Buhari Ke Si Awon Gomina Apa Ariwa Pe Ki Won Pese Eto Aabo To Peye Sagbegbe Won

Aare Muhammadu Buhari ti soodi mimo fun awon Gomina meje to wa lapa ariwa iwooorun orileede yip e ki won tete lo wa ona ti opin yio fi ba ose tawon agbebon nse lagbegbe naa.

Gomina ipinle Kebbi, Atiku Bagudu lo foju oro yi lede lasiko ipade awon ti oro Alafia eti aabo, ati isokan gberu, eyi to waye nilu Birmin Kebbi.

Gomina Bagudu salaye wi pe ikede Aare yi lo da lori ati fi le rii daju pe ohun gbogbo te te pada bo sipo lagbegbe naa.

O soo di mimo wipe Aare ko fi owo kekere mu eto aabo emi ati dukia araalu, leyi tii se ipenija to n koju ile yi.

Gomina naa wa salaye wipe ojure tolori telemu ni oro eto aabo, ati pe gbogbo igbese lo gbodo je gbigbe lori ati bori isoro naa.

Net/Salaudeen

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *