-
Amofin Pe Fun Ipese Eto Eko to Yekooro fun Awon Omode Ile Adulawo
Amofin kan, Ogbeni Afolabi Amure ti pe fun ofin ti yio so iye awon ti, lokolaya to fe segbayawo lebi, leyi ti o ni ko gbodo ju meji lo, ki won baa lee to won bo se ye. O pe ipe yi ninu iforowero re pelu akoroyin ile ise Radio Nigeria lori ayajo ojo awon …