Yoruba

Amofin Pe Fun Ipese Eto Eko to Yekooro fun Awon Omode Ile Adulawo

Amofin kan, Ogbeni Afolabi Amure ti pe fun ofin ti yio so iye awon ti,  lokolaya to fe segbayawo lebi, leyi ti o ni ko gbodo ju meji lo, ki won baa  lee to won bo se ye.

O pe ipe yi ninu iforowero re pelu akoroyin ile ise Radio Nigeria lori ayajo ojo awon  omo ile Adulawo lagbaye.

Ogbeni Amure tenumo wipe awon obi ati awon ti won sese fe segbeyawo ni won gbodo kilo fun lati yago fun bibi awon ti won o nile too daradara.

Ogbeni Amure ni eto awon omode ni ofin ile yii o figbakanbokan ninu lori re, ti o ni o yeki gbogbo awon toro kan si rii daju wipe won o te awon eto wonyi loju.

Akori ayajo todun yi ni “Nini anfani si eto igbejo to gba tomode ro nile Adulawo”.

Oluwayemisi Dada

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *