Iyawo Gomina Ipinle Oyo, Arabinrin Tamunominimi Makinde ti kesi awon omo ile Nigeria pe ki won dide atileyin fawon obinrin to lugbadi ijamba lasiko abe dida fomobirin. Arabinrin Makinde soro imoran yi lasiko eto ayajo fifopin si abe dida fomobinrin fun todun yi. Iyawo Gomina, eni ti alakoso Continue Reading
Kòdín ní ẹgbẹ̀rún mẹ́ta èèyàn ló ti jànfàní ètò ìrónilágbára ti ó fisi aya Gómìnà ìpínlẹ̀ ọ̀yọ́, Arábìnrin Tamunọminini Makinde gbé kalẹ̀ nípinlẹ̀ yí. Àwọn tó jànfàní ètò náà ni wọ́n kójọ jákèjádò ìjọba ìbílẹ̀ mẹ́tàlélọ́gbọ̀n tón bẹ nípinlẹ̀ ọ̀yọ́. Ètò ìrónilágbára náà ló wáyé láwọn ìlú ní ẹkùn Ìbàràpá, Ogbomosọ, Ọyọ, Saki. Isẹyin, àti […]Continue Reading