Home Posts tagged Bank of Industry
Yoruba

Ilé Ìfowópamọ́ Ró Àwọn Olùdókòwò L’ágbára N’ípinlẹ̀ Èkìtì

Bánki tón rísí àwọn ilésẹ́ olókowò, ọ̀hún ti satán láti pèsè owóya tí yo wọ billiọnu kan naira láti ró àwọn onísòwò lágbára nípinlẹ̀ Èkìtì. Olùdarí àgbà fún ilé ìfowópamọ́ náà, nípinlẹ̀ Òndó àti Èkìtì, ọ̀gbẹ́ni Seyi Ashaolu ló jẹ́ kọ́rọ̀ yi di mímọ̀ nílu Adó-Èkìtì, tọ́kasi pé bánki náà setán láti yá àwọn olókowò […]Continue Reading