Yoruba

Ijoba apapo pelu ajosepo banky agbaye, yoo pin egberindinlaadota million dollar ni ipinle merindinlogoji to w anile yi, lati madinku ba ipa aarun covid-19.

Alakoso keji feto isunaa ati aato gbogbo, Ogbeni Clem Agba so eyi nilu Abuja.

O salaye pe, ipinle kokan yoo gba ogun million dollar, nigba tii million medoogun dollar yo je tolu-ilu yii FCT.

Alakoso Agba fikun pe, igbese naa waaye lati mu agbende ba eto oro-aje nibamu pelu mimu ileri Aare Buhari se nidi yiyo million mewa omo ile Nigeria kuro ninu ise ati osi.

Elizabeth Idogbe

Yoruba

Ijoba ipinle Eko ti so pee to iranwo eyi ti banki Agbaye gbe kale lati mu kagbega deba akowo ati igbaye gbadun araalu, ni yo se atileyin fun ise akanse kilo opopona to wo oko to le ni ibuso agbegbe oko merin otooto.

Alakoso feto ogbin nipinle Eko, Arabinrin Abisola Olusanya, lo je koro yi di mimo ni ikeja.

Arabinrin Olusanya so pea won agbegbe oko mereerin naa ni Igbodu nilu Epe, Araga to ni Epe bakanna, Erinkorodu nilu Korodu to fimo Afowo ni Badagry.

O tokasi pea won onl ero ti bere ise lori opopna mereerin lati mo pato iye ti won yon na lee lori ti ise yoo sib ere leye o soka.

Afonja

News Yoruba

Ijoba apapo sope iro tojina soo too nii abo iwadi banki agbaye tonii, ida mejidinlogorin awon onibara ilesa ina oba lorilede yii ni ki ni ina –oba fun wakati mejila loojo.

 Olubadamoran Pataki saare foro igbayegbadun , ogbeni ahmad zakari enito soro yii nilu Abuja, sope koye won  liana isiro ti banki agbaye  lo lori oro ohun.

Ogbeni zakari wa fikun pe akosile latedo ajo tro nrisi oro ina mona – mona , NERC fihan pe ida maruunle ladota awon omo ile yii , ti won nlo ina oba niwon wa nisori D ati E ti won kin ina tootoo wakati mejila lojumo.

Net/ Idogbe

Yoruba

Banki agbaye ti buwolu owoya oni millionu eedegberin o le ni aadota, 750 million dollars ti egbe to wa fun idagbasoke lagbaye fun agbedide eka ina oba nile Naijiria.

Ninu atejade ti banki naa fi sita nilu Abuja, o ni igbese naa ni won gbe lati lee ri pe eka ina oba tubo fese rinle ki won si lee ko akoyawo.

Atejade naa salaye wipe ida metadinlaadota awon omo ile yi ni won ni anfani si ina oba nigbati awon ti won nni nkoju idakuruku ina oba.

O fikun wipe, sisatunse si eka ina oba ni paapajulo fun awon eka to npese nkan nile yi se pataki lati muki oro aje tubo gbooro sii leyin ajakale arun Covid-19.

Yemisi Dada