Home Posts tagged Birgitt Ory
Yoruba

Àarẹ Buhari késí ilẹ̀ òkèrè láti dọwọ́pọ̀ pẹ̀lú ilẹ̀ Nàijírìa

Àarẹ Muhammadu Buhari ti rọ àwọn olùdóokowò láti orílẹ̀dè Germeny pé kíwọ́n wá gbé ilésẹ́ ajé kalẹ̀ papáà lẹ́ka ohun àmúságbara. Nígbà tó ńgba ìwé ìwosẹ́ látọ̀dọ̀ asojú ilẹ̀ Germany sórílẹ̀èdè Nàijírìa Birgitt Ory, nílé àarẹ Buhari fọwọ́ ìdánilójú sọ̀yà fáwọn oní ilésẹ́ ajé láti orílẹ̀èdè Continue Reading