Home Posts tagged Bọ́bajíròrò
News Yoruba

Àwọn Èèkàn Àwùjọ Kẹ́dùn Ìpapòdà Bọ́bajírò Tìlú ’Bàdàn.

Àwọn èkàn nílẹ̀ yí ti bẹ̀rẹ̀ siní fi èrò wọn hàn lórí ìpapòdà akọ̀wé tẹ́lẹ̀rí fún ìjọna ológun lẹ́kùn ìwọ̀ orun àtijọ́ nílẹ̀ Nàijírìa, olóòyè Theophilus Akinyẹle. Nínú ọ̀rọ̀ rẹ̀, akọ̀wé tẹ́lẹ̀rí fún ìjọba ìpínlẹ̀ ọ̀yọ́, olóòyè Bisi Adesọla sàpèjúwe olóògbe Akinyẹle gẹ́gẹ́bí akínkajú ẹ̀dá, tójẹ́ Continue Reading