Home Posts tagged Collapsed Building
Yoruba

Gómìnà Sanwo-Olu pàsẹ ìgb’wsẹ̀ ìwádi ní kíkún lórí ohun tó sokùnfà ilé wíwó nílu èkó.

Gómìnà Ìpínlẹ̀, Èkó, ọ̀gbẹ́ni Babajide Sanwo-Olu ti pàsẹ ìgbésẹ̀ ìwádi ní kíkún lórí ohun tó sokùnfà ilé alájà mọ́kàndílógúntó dàwólulẹ̀ nípinlẹ̀ Èkó. Àtẹ̀jádé kan tálákoso fétò ìròyìn àtáàtò gbogbo nípinlẹ̀ náà, ọ̀gbẹ́ni Gbenga Ọmọtọsọ, fisita, lóti tọ́kasi pé, ìgbésẹ̀ ìwádíì náà ni yóò jẹ́kí wọ́n mọ̀ ohun tó sokùnfà bílé ńlá náà se dàwó lulẹ̀, […]Continue Reading