Home Posts tagged Court of Appeal
Yoruba

Ilé Ẹjọ́ kòtẹ́milọ́rùn ti gbé ìgbẹ́jọ́ kalẹ̀ lórí ẹjọ́ àwọn alága ìjọba ìbílẹ̀

Ilé ẹjọ́ kòtẹ́milọ́rùn ti da ìgbẹ́jọ́ ìgbẹ́jọ́ ilé ẹjọ́ gíga tí ìpínlẹ̀ ọ̀yọ́ gbé kalẹ̀ tó ka ìjọba ìpínlẹ̀ ọ̀yọ́ lápákò láti júwe ilé fún àwọn alága ìjọba ìbílẹ̀ nù. Ilé ẹjọ́ náà ní ìgbẹ́jọ́ tí ilé ẹjọ́ gíga gbé kalẹ̀ ni wọ́n gbé lórí ountí wọ́n lérò léyi tí wọ́n kò lee gbà wọlé. […]Continue Reading