Home Posts tagged Cyril Ramaphosa
Yoruba
Àarẹ Muhammadu Buhari ti gba ẹ̀bẹ̀ àarẹ orílẹ̀èdè South-Africa, Cyril Ramaphosa sí ilẹ̀ yíì, lórí ìkọlù tówáyé lórílẹ̀dè náà. Àarẹ Buhari ẹnitó sàpèjúwe ìkọlù náà gẹ́gẹ́ bí èyító burú jai, fọwọ́ ìdánilójú sọ̀yà pé, ìbásepọ̀ tódánmọ́rán yóò wáyé lọ́tun l’árin àwọn orílẹ̀èdè méjèjì. Ó mu wá sí ìrántí pé, ilẹ̀ Nàijírìa kó ipa takun-takun fún […]Read More...
Load More