Home Posts tagged Dame Tallen
Yoruba

Alákoso foro obinrin pe fun wíwójùtú sí ìpèníja àwọn ọmọdé.

Alákoso fọ́rọ̀ àwọn obìnrin, arábìnrin Dame Tallen ti késí ìjọba àtàwọn tọ́rọ̀kàn láti wojùtú sí ìdúnkokò mọ́ ìgbáyégbádùn àwọn ọmọdé nílẹ̀ Nàijírìa èyí tí ìbẹ́sílẹ̀ àrùn Covid19 ńfà. Alákoso sọ̀rọ̀ yí , nínú ọ̀rọ̀ rẹ̀ láti se ayẹyẹ àyájọ́ àwọn ọmọdé lágbeyé tó kò lóni. Arábìnrin Tallen ńfẹ́ kí Continue Reading