Home Posts tagged Dolapo Ogunsola
Yoruba

Àwọn èyàn ti ńfi èrò wọn hàn lórí ìdájọ́ ilé ẹjọ́ kòtẹ́milọ́rùn

Onímọ̀ nípa òsèlú kan, ọ̀gbẹ́ni Dọlapọ Ogunsọla ti sàpèjúwe, rògbòdìyàn tón wáyé nínú ẹgbẹ́ òsèlú,APC, nípinlẹ̀ Ẹdo gẹ́gẹ́bí èyí tí kò ní nípa rere fún ẹgbẹ́ náà pẹ̀lú ìbò sípò Gómìnà tí wọ́n ńgbaradì fún. Ó sọ̀rọ̀ yí lásìkò tón bá akọ̀ròyìn ilésẹ́ Radio Nigeria sọ̀rọ̀, lórí bí ilé ẹjọ́ Continue Reading