Home Posts tagged Dr Chukwe Iheweazu
Yoruba

Àjọ NCDC Pa Ní Dandan Fún Àwọn Àgùnbánirọ̀ Láti S’àyẹ̀wò COVID-19

Káabo tó péye le wà láwọn ibùdó ìfinimọ́lé fáwọn àgùnbánirọ̀ yíká orílẹ̀èdè yí, àjọ tón gbógunti ìtànkẹ́lẹ̀ àrùn ti sọpé gbogbo àwọn tó fẹ́ sìnrúlu ni wọ́n yo se àyẹ̀wò fun nípa irinsẹ́ tuntun fún síse àyẹ̀wò fún àrùn COVID-19. Olùdarí àjọ náà Ọ̀mọ̀wé Chukwe Ihekweazu ló sọ̀rọ̀ yí lásìkò tón Continue Reading