Home Posts tagged Dr Folsade Yemi-Esan
Yoruba

Ìjọba àpapọ̀ ti pàsẹ fáwọn àjọ aláabo, láti fàsẹ kónílé ógbélé múlẹ̀ fáwọn òsìsẹ́

Ìjọba àpapọ̀ ti pàsẹ fáwọn àjọ aláàbo tó wà láwọn ẹnu ìloro àwọn ilé-isẹ́ ìjọba látiridájú pé, àwọn òsìsẹ́ ìjọba tó wà lákàsọ̀ kẹtàlá sókè niwọn gba láàye láti wọ àyíká àwọn ilé-isẹ́ ọ̀hún. Èyí ló wáyé nípasẹ̀ àsẹ tígbìmọ̀ amúsẹ́yá ilé isẹ́ àarẹ lórí covid 19, pé káwọn òsìsẹ́ tó wà lákàsọ̀ Continue Reading