Home Posts tagged Dr Olajide Oladipupo
Yoruba

Onímò ìlera gbamoran lórí àrun Lassa

Onímò nípa isegun kan, Dókítà Olajide Oladipupo ti niki àwọn ènìyàn mú imotótó lókunkúndùn láti leè dènà àìsàn ibà ọ̀rẹ̀rẹ̀. Dókítà Oladipupo sọ̀rọ̀ yi nínú iforowero pẹ̀lú akoroyin agbègbè àti ìgberíko nilu Ìbàdàn. Ó fi aidunu rè hàn sí bí àwọn èèyàn kìí se kọbiara sí ìlera wọn ní paapajulo Continue Reading