-
Gomina Makinde Beere Fun Ajosepo Awon Omo Egbe Oselu PDP
Gomina Ipinle Oyo, Onimo ero Seyi Makinde tip e awon oloye tuntun egbe oselu PDP fekun guusu iwoorun ile yi nija pe ki won rii daju pe ajosepo to danmoran wa laarin awon omo egbe to n fi apa janu. O soro yi lasiko eto ibura fun awon oloye tuntun naa nile egbe oselu PDP…