O se Pataki ki ajosepo was laarin ijoba ni gbogbo eka ati ileese aladani lati mu ki amugbooro de ba nini anfani si eto ilera to koju owo. Igbakeji Aare, Ojogbon Yemi Osinbajo lo soro yi lasiko to n siso loju ipade apero eto ilera alabode kan nilu Abuja. Ojogbon Osinbajo tenumo pe ibasepo laarin Continue Reading
Àjọ tó rísí ètò ìlera nípinll Èkó sọpé, ohun ti ńgbé ìgbésẹ̀ láti sàfikún àwọn olùgbé tóòtóò milliọnu mẹ́ta sínú ìlànà ètò ìlera adójútófo ti ìforúkọsílẹ̀ náà yóò sì wáyé lárin ọdún kan. Alákoso àgbà fájọ ọ̀hún Dókítà Emmanuẹla Zamba, sọ èyí di mímọ̀ níbi ìpàdé ètò ìlanilọ́yẹ̀ àwọn èèyàn ẹsẹ kùkú àti ìgbésẹ̀ iforukọ […]Continue Reading
Awon eeyan ipinle Oyo toleni egberun lona igba lo je anfani eto ilera ofe eyiti ilese eto ilera ipinle oyo ati ajosepo eto ilera ofe omititun sagbekale re. Eto ohun eyi to bere ni ijoba ibile ila –oorun ibarapa nipinle oyo, lawon eeyan jnafani itoju ofe lori okojokan aisan bi, iba, eje riru, ipenija eyin […]Continue Reading