News

Ìpinle eko gbé ìgbésẹ̀ láti forúkọ milliọnu mẹ́ta àwọn olùgbé sínú ìlànà adójútófo ètò-ìlera

Àjọ tó rísí ètò ìlera nípinll Èkó sọpé, ohun ti ńgbé ìgbésẹ̀ láti sàfikún àwọn olùgbé tóòtóò milliọnu mẹ́ta sínú ìlànà ètò ìlera adójútófo ti ìforúkọsílẹ̀ náà yóò sì wáyé lárin ọdún kan.

Alákoso àgbà fájọ ọ̀hún Dókítà Emmanuẹla Zamba, sọ èyí di mímọ̀ níbi ìpàdé ètò ìlanilọ́yẹ̀ àwọn èèyàn ẹsẹ kùkú àti ìgbésẹ̀ iforukọ sílẹ̀ tó wáyé nípinlẹ̀ náà.

Díkítà Zamba ẹnitó sàlàyé pé, ètò ìlanilọ́yẹ̀ àti iforukọ sílẹ̀ ọ̀hún sepàtàkì nítirípé ìlera lọrọ̀ àtọ́kasí.

Àwọn irinsẹ́ toye pe okolerugbaole méjì ló ti wan kanlẹ láti sètò iforukọ sílẹ̀ ná. Elizabeth Idogbe

pub-5160901092443552

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *