Home Posts tagged ètò ìlera
News Yoruba

Àwọn tọ́rọkàn ti késíjọba láti wójùtú sọ́rọ̀ báwọn akọsẹ́mọsẹ́ lẹ́ka ètò ìlera se máà ń sá ròkè òkun.

Àwọn èekàn tọ́rọkàn ti láwọn ńfẹ́ kíjọba tètè wójùtú sọ́rọ̀ báwọn akọ́sẹ́mọsẹ́ lẹ́ka ètò ìlera se máà ń sáré lọ sókè òkun, láti dènà ewu tólè tìdí rẹ̀ súyọ. Nínú ìfọ̀rọ̀wánilẹ́nuwò ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀ pẹ̀lú ilé-isẹ́ wa Radio Nigeria, wọ́n tọ́kasi pé, ìgbésẹ̀ yíì se pàtàkì fún ilẹ̀ Nàijírìa, lọ́nà àti Continue Reading