Home Posts tagged Ètò ìwóde
Yoruba

Ètò ìwóde Egbé àwon òsìsé, NLC, wáyé yíká àwon ìpínlè ílè yí

Ètò ìwóde Egbé àwon òsìsé NLC ti wáyé yíká àwon ìpínlè lorilede yí.  Ètò ìwóde náà tegbe àwon òsìsé gùnlé lo wáyé láti fi sàtìleyìn fun ìyansélódì Egbé ASUU to nlo lówó, tíwón si tún fi n sàfihàn àìdùnú lori owó tíjoba àpapò mórò ìyansélódì olósè méjìlá Egbé ASUU náà. Àbò ìròyìn láti àwon Continue Reading