Home Posts tagged Federal School
Yoruba

Asòfin dába atungbeyewo àte ètò ẹ̀kọ́

Olórí ilé ìgbìmò asofin nílè yíì Senato Almad Lawan ti késí àwọn olùdarí ilé ìwé lorileèdè yi láti sátúngbeyẹ̀wò àte ètò ẹ̀kọ́ ní gbogbo ẹ̀ka ètò ẹ̀kọ́ nílè yi. Senato Lawan dába ọ̀rọ̀ yi nígbàtí ó nside ìjóko gbogbogbo lórí Ijíròrò lórí àbá òfin tí wọ́n fẹ́ fi ṣàgbékale àwọn ilé ẹ̀kọ́ gíga Continue Reading