Olórí ilé ìgbìmò asofin nílè yíì Senato Almad Lawan ti késí àwọn olùdarí ilé ìwé lorileèdè yi láti sátúngbeyẹ̀wò àte ètò ẹ̀kọ́ ní gbogbo ẹ̀ka ètò ẹ̀kọ́ nílè yi.

Senato Lawan dába ọ̀rọ̀ yi nígbàtí ó nside ìjóko gbogbogbo lórí Ijíròrò lórí àbá òfin tí wọ́n fẹ́ fi ṣàgbékale àwọn ilé ẹ̀kọ́ gíga ìjọba àpapọ̀.

Ó ní àte ètò ẹ̀kọ́ ilẹ̀ yí tí nílò atungbeyewo tipetipe láti leè ta kangbọn ní ṣáá taa wà yi. 

Senato Lawan ni orílè èdè Nàìjíríà nílò àwọn olùkọ́ tí wọ́n bá òde òní mu ní pàájùlọ ní ìlànà ti ìgbàlódé.

Àwọn ilé ẹ̀kọ́ gíga mẹ́ta oun ni ilé ẹ̀kọ́ olukoni àpapò, Giwa ńipinle Kaduna, ilé ẹ̀kọ́ olukoni apapo Mutu Biyu ní ìpínlè Taraba àti ti Ibokun ńipinle Osun.

Yemisi Dada/Kemi Ogunkola

pub-5160901092443552

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *