Home Posts tagged Hameed Ali
Yoruba

Iléésẹ́ asọ́bodè fòfin de kíkó ọja wọlé látẹnu ìloro wọ ilẹ̀ wa

Iléésẹ́ asọ́bodè nílẹ̀ yíì, ti kéde fífòfinde láinigbèdéke lórí kíkó ọjà wọlé tàbì fífi ọjà sọwọ́ sílẹ̀ òkèrè láti ẹnu bodè ilẹ̀ yíì. Ọga-àgbà fúnleesẹ́ as abodè, Ọ̀gágun Fẹ̀yìntì Hameed Ali, ẹni tó sọ̀rọ̀ yíì níbi ìpàdé àwọn oníròyìn tówáyé nílu Abuja, sọpé ilé olómìnìra Niger náà ti fòfinde Continue Reading