Ilé isẹ́ ọmọ ológun orílẹ̀dè yíì, ti ké sáwọn aráalu láti máà se fòyà rárá lórí ìgbésẹ̀ ìbọn yínyìn tí yóò wáyé lákokò ayẹyẹ àyájọ́ òmìnira ilẹ̀ fún tọdún 2019 tawàyí. Èyí ló jẹyọ nínú àtẹ̀jáde kan tígbákejì olùdarí agbẹnusọ fún ilé-isẹ́ ológun náà, ọ̀gágun Haruna Tagwai fisíta nílu Abuja. Continue Reading