Ijoba Ipinle Oyo ti bere eto idanileko fawon Kanselo to to oodunrun ati mokanlelaadota pelu awon akowe metalelogbon to je ti ile asofin ijoba ibile. Eto idanileko naa lo da lori liana isejoba rere nijoba ibile ati idesemulle liana asotele onikoko merin ijoba to wa lode nipinle Oyo. Nigba to n Continue Reading