Home Posts tagged ìgbìmọ̀ ọ̀hún
Yoruba

Ilé asòfin ní kí ọ̀gá Bánki àpapọ̀ farahàn lórí àkànse isẹ́

Ìgbìmọ̀ tẹkótó ilé tó ńrísí idàgbàsókè ẹkùn Niger Dẹlta, NDDC, ti kanpá fún ọ̀gá àgbà bánki àpapọ̀ ilẹ̀ yíì Godwin Emefiele láti farahàn níwájú ilé. Alága, ìgbìmọ̀ ọ̀hún, ọ̀gbẹ́ni Nicholas Ossai, sọ fáwọn oníròyìn nílu Abuja, wípé àwọn ti gba àkọsílẹ̀ láti ilésẹ́ bánki àpapọ̀ lórí àwọn isẹ́ Continue Reading