Home Posts tagged ìgbìmọ̀ tó ńrísí ìgbaninímọ̀ràn fétò ọrọ̀-ajé EAC
Yoruba
Ẹgbẹ́ àwọn tó ńpèsè ǹkan nílẹ̀ Nàijírìa MAN, sọ pé àtúntò tówáyé lẹ́ka ìgbìmọ̀ tó ńrísí ìgbaninímọ̀ràn fétò ọrọ̀-ajé EAC, látọwọ́ àarẹ Buhari jẹ́ èyí tódara gba, lákokò tó yẹ tó sì ńfìdí ìpinu àarẹ fétò ọrọ̀-ajé tó dúró re múlẹ̀. Nínú àtẹ̀jáde kan tólùdarí àgbà fẹ́gbẹ́ MAN, ọ̀gbẹ́ni Muda Yusuf fisíta ó pèfún àtúnyẹ̀wò […]Read More...
Load More