Ileese olopa nipinle Osun ti so pe ko si ooto oro ninu iroyin to fie sun kan awako kan pe oji ero mejidinlofun ninu oko re lo, fun awon ajinigbe nipinle Ekiti. Agbenuso ileese ohun, nipinle Osun Yemisi Opalola, ninu atejade to fisita, so pe kosi enikeni to wa fi ejo naa to ileese olopa […]Continue Reading
Osun State Police Command has debunked the media report about a driver who allegedly sold eighteen passengers to kidnappers in Ekiti state. A statement by the Police Public Relations Officer in the state, Mrs Yemisi Opalola indicates that there was no such case reported in Ijamo, nor any other Police Station in Osun State describing […]Continue Reading