Yoruba

Ileese Olopa Ipinle Osun Ni Ko Si Ooto Ninu Oro Pe Awako Ta Awon Ero Fun Ajinigbe

Ileese olopa nipinle Osun ti so pe ko si ooto oro ninu iroyin to fie sun kan awako kan pe oji ero mejidinlofun ninu oko re lo, fun awon ajinigbe nipinle Ekiti.

Agbenuso ileese ohun, nipinle Osun Yemisi Opalola, ninu atejade to fisita, so pe kosi enikeni to wa fi ejo naa to ileese olopa lati nitibutoro ipinle Osun.

Atejade naa see lakaye pe, lasiko tawon ero inu oko fe doola awon to n bo lati ilu Abuja ti won ni ijamba oko ni Efon Alaye, ni awako naa jawon sile nibe, to si lo pelu eru ati nkan ini awon ero yi to si wa ninu oko re.

Gegebi atejade naa tiwi, owo agbofinro tite awako yi.

Ileese Olopa ipinle Osun ti war o awon eyan awujo lati kotikun si iroyin eke, to si sekilo lori titan aheso oro kakari.

Isaac Haastrup/Ololade Afonja

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *