Ijoba Ipinle Eko nipase ajo to n mojuto imototo ayika, LASEPA, ti ro awon eni orokan leka ipese nkan lori amojuto awon kemika to lewu. Oga agba ajo LASEPA, Omowe Dolapo Fasawe, to soro naa lasiko eto idanileko awon eni-orokan nilu Eko, wa pe awon olupese nkan nija lati je akosemose lori ise ti Continue Reading
Igbimo to nri si sunkere fakere oko nipinle Eko, LASTMA ti kede titipa oju ona Ahmadu Bello si Adeola Odeku to fi mo Adetokunbo Ademola. Alakoso agba fun igbimo LASTMA, Ogbeni Bolaji Oreagba so eyi ninu atejade kan nilu Eko. Atejade ohun ni oju opopona ohun yoo je titipa fun igba die, ti lilo bibo […]Continue Reading
Ijoba ipinle Eko ti ya owo to le ni billionu kan naira soto fun eko o fe lodun 2021, fun awon to je omo bibi ipinle Eko to w anile eko giga yika ile yi. Akowe agba fun ileese to n mojuto eko ofe nipinle Eko, Ogbeni Omotayo Fakolujo soro yi lasiko to n baa […]Continue Reading
Ijoba ipinle Eko ti salaye igbaradi re ati se atungbende ofin to de awon to n fi okada gbe ero. Alakoso eto iroyin fin Ipinle Eko, Ogbeni Gbenga Omotoso lo kede oro yin ni Ikeja pelu alaye wi pe, ofin eto irina Ipinle Eko todun 2018 lo fofinde igbokegbodo awon to n fi okada gbe […]Continue Reading