Home Posts tagged Ìjọba ìpínlẹ̀ Ọsun
Yoruba

Ìjọba ìpínlẹ̀ Ọsun fẹ́ sàgbékalẹ̀ ilé ẹjọ́ alágbeká làtidènà ìtànkálẹ̀ àrùn Covid-19

Ìjọba ìpínlẹ̀ Ọsun ti ńgba lérò láti se àgbékalẹ̀ ilé ẹjọ́ alágbekákiri yípo ìpínlẹ̀ náà, pẹ̀lú bí iye àwọn tó ńkóti si títẹ̀lé àlàkalẹ̀ èyí tí àjọ NCDC gbé kalẹ̀ láti fòpin sí àrùn covid-19, se ń pọ̀si Ìjọba sọ pé, àwọn tọ́wọ́ bátẹ̀ ni wọ́n yo sisẹ́ ìlú fún, iye àwọn wákàtí tí wọ́n […]Continue Reading