Yoruba

Ìjọba ìpínlẹ̀ Ọsun fẹ́ sàgbékalẹ̀ ilé ẹjọ́ alágbeká làtidènà ìtànkálẹ̀ àrùn Covid-19

Ìjọba ìpínlẹ̀ Ọsun ti ńgba lérò láti se àgbékalẹ̀ ilé ẹjọ́ alágbekákiri yípo ìpínlẹ̀ náà, pẹ̀lú bí iye àwọn tó ńkóti si títẹ̀lé àlàkalẹ̀ èyí tí àjọ NCDC gbé kalẹ̀ láti fòpin sí àrùn covid-19, se ń pọ̀si

Ìjọba sọ pé, àwọn tọ́wọ́ bátẹ̀ ni wọ́n yo sisẹ́ ìlú fún, iye àwọn wákàtí tí wọ́n bá là kalẹ̀, dípò tí wọ́n yo fi san owó ìtanràn.

Nínú àtẹ̀jádé èyí tí alákoso fọ́rọ̀ ìròyìn àti ìlanilọ́yẹ̀ Funkẹ Ẹgbẹmọde fọwọ́sí fi àidùnú rẹ̀ hàn lórí bọ́pọ̀ èyàn se ń lọ sarin àwùjọlái lo ìbòmú táwọn miràn sìtún se ayẹyẹ.

Nínú ọ̀rọ̀ miràn ẹ̀wẹ̀, ìgbìmọ̀ tón rísí dídànà ìtànkálẹ̀ àrùn nínú ìpàdé tí wọ́n se, jiroro lori sise ilewe pada nipinle Osun.

Afonja

pub-5160901092443552

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *