Home Posts tagged Ilé Isẹ́ Panápaná
News Yoruba

Ìjọba Àpapọ̀ Yóò Kojú Oro Sáwọn Tó Bá Ń Ba Dúkia Ilé Isẹ́ Panápaná Jẹ́

Alákoso fọ́rọ̀ abẹ́lé, ọ̀gbẹ́ni Rauf Arẹgbẹsọla ti sọpé ìjọba àpapọ̀ yóò sisẹ́ lórí àwọn ọ̀daràn tó n sèkọlù sí àwọn òsìsẹ́ panápaná àti àwọn dúkia ilé isẹ́ náà jákèjádò ilẹ̀ Nàijírìa. Ọgbẹni Arẹgbẹsọla yọjú ọ̀rọ̀ náà síta lásìkò tón sísọ lójú ọkọ̀ panápaná olówó iyebíye tuntun tíjọba àpapọ̀ kó Continue Reading