Home Posts tagged ilé-isẹ́ Radio Nigeria
Yoruba

Àbẹ̀wò Ìbánikedùn Ikọ̀ Alábútó Ilé Isẹ́ Radio Nigeria Ìbàdàn

Ikọ̀ alábójútó ilé-isẹ́ Radio Nigeria àpapọ̀ ilẹ̀ wa, lẹ́kùn ìbàdàn, ti se ìbánikẹ́dùn pẹ̀lú àwọn èèyàn ilẹ̀ ìbàdàn àti ìpìnlẹ̀ ọ̀yọ́ lápapọ̀ lórí ìpopòdà Olúbàdàn tilẹ̀ ìbàdàn Ọba Saliu Adetunji, tó darapọ̀  máwọn babanla rẹ̀ lána òde yíì. Ètò ìbánikẹ́dùn náà niwọ́n se lọ sáàfin olúbàdàn Continue Reading