-
Awon ilese agbofinro ileyi jinna sesekuku – Gomina Oyetola
Gomina ipinle Osun, Ogbeni Adegboyega Oyetola ti so di mimo pe ona kan soso tile yi fi lee wa ojutu is ipenija eto aabo ni pinpin agbara nilana ile ise olopa. Gomina Oyetola soju oro yi lede nilu Abuja pelu alaye wipe awon ileese agbofinro ile yi lo je pe ojukan ni agbara won sodo…