Home Posts tagged Ilésẹ́ ọlọ́pa
News Yoruba

Ilésẹ́ ọlọ́pa nípinlẹ̀ Ògùn nawọ́ gán àwọn tíwọ́n furasí pé wọ́n gbẹ̀mí òsìsẹ́ ọlọ́pa kan.

Ọwọ́ sìkún ilésẹ́ ọlọ́pa nípinlẹ̀ Ògùn ti tẹ àwọn mẹ́rin tíwọ́n furasí wípé wọ́n lọ́wọ́ nínú bíwọ́n senáà òsìsẹ́ ọlọ́pa, ọ̀gbẹ́ni Agada Akoh tí wọ́n sì gbẹ̀mí rẹ̀ lágbègbè dálémọ Sángo Ọtta nípinlẹ̀ Ògùn. Nínú àtẹjade kan tí agbẹnusọ ilásẹ ọlọpa nípinlẹ Ògùn, ọgbẹni Abimbọla Oyeyẹmi fisíta Continue Reading