Home Posts tagged Iwo oorun-Guusu
Yoruba

Ìjọba Apapọ̀ Ti Gbé Orùkọ́ Ipínlẹ̀ Mọ́kànlélógún Jáde Ti Wọ́n Yo Ni Ibùdó Iselọ́jọ̀ Fún Kíkó Eran Jẹ̀

Pẹ̀lú bí ìgbésẹ̀ láti mú àyípadà dé bá ńkan ọ̀sìn nílẹ̀ yí, ìjọba àpapọ̀ ti ní kí ibùdó tí wọ́n yo ti ma kẹ́ran jẹ̀, tí wọ́n yà sọ́tọ̀, kó gbérasọ, nípinlẹ̀ mọ́kàndínlógún láriwá ilẹ̀ yí, tófimọ́ ìpínlẹ̀ ọ̀yọ́ àti Ògùn lẹ́kùn ìwọ̀ orun gúsù ilẹ̀ yí. Nígbà tón sọ̀rọ̀ nílu Abuja, lásìkò ìpàdé Continue Reading