Home Posts tagged Julie Okah-Donli
Yoruba

Àjọ NAPTIP Gùnlé Ètò Ìdánilẹ́kọ Fáwọn Òsìsẹ́ Rẹ̀ Láti Gbógun Ti Ìwà Ìfinisòwò Lọ́nà Àitọ́

Àjọ tón gbógun ti fífi èyàn sòwò lọ́nà àitọ́, ti bẹ̀rẹ̀ ìdánilẹ́kọ fún àwọn òsìsẹ́ nípinlẹ̀ lórí gbígbógun ti gbígbé àwọn èyàn kúrò lórílẹ̀èdè yíì lọ́nà àitọ́. Olùdarí àgbà fájọ ọ̀hún Arábìnrin Julie Okah-Donli ló sọ eléyíì di mímọ̀ lásìkò ìdánilẹ́kọ tó wáyé nílu Èkó, tó sì sàpèjúwe ìdásílẹ̀ Continue Reading