Home Posts tagged Khasinoggi
Yoruba

Biden Yio Sèpàdé Pọ̀ Pẹ̀lú Asáàjú Ilẹ̀ Palestine, Saudi Arabia

Àarẹ ilẹ̀ America, Joe Biden ni yio se pàdépọ̀ pẹ̀lú àwọn adarí ilẹ̀ Palestine tí wọ́n wà lágbègbè West Bank lóni sáàjú kó tó lọ síbi ìpàdé àpérò ni Saudi Arabia. Gẹ́gẹ́bí ohuntí àwọn ònwòye sọ, ó seese kí ǹkan lọ́ jái níbi ìpàdé náà pẹ̀lú Mahmoud Abbas nítorí gbúngbùngbún tó wà láàrin wọn Continue Reading