Home Posts tagged Mile 2
Yoruba
Ìjọba ìpínlẹ̀ Èkó ti sọpé gbogbo òpópónà àti afárá èyí tí wọ́n ńkọ́ lọ́wọ́ ládugbò Apapa ni yo jẹ píparí nínú osù kẹwa ọdún tawàyí. Gómìnà Babajide Sanwo-olu ló sọ̀rọ̀ ìdánilójú yi lásìkò tó se àbẹ̀wò láti mọ ibi tísẹ́ dé dúró lágbègbè náà, n’ípinlẹ̀ Èkó. Gómìnà Sanwo-olu, sọpé súnkẹrẹ f’àkẹrẹ ọkọ̀, tón f’ojúmọ́ faye […]Read More...
Load More