Home Posts tagged Mr Imoh Etuk
Yoruba

Àjọ FRSC Sèkìlọ̀ rírọrase lójú pópó láti dènà ìjàmbá ọkọ lósù bà-bà-bà

Àjọ ẹ̀sọ́ ojú pópó, FRSC, ti rọ àwọn tó ńsàmúlò ojú òpópónà, láti máà sọ́ráàse lásìkò osù bà-bà-bà láti dènà ìjàmbà ọkọ̀ ikú òjijì àti ìfarapa. Ọga n’ílesẹ́ náà, lẹ́kùn Èkó àti Ògùn, ọ̀gbẹ́ni Imoh Etuk sọ̀rọ̀ yíì níbi ìfilọ́lẹ̀ ètò ìlanilọ́yẹ̀ osù bà-bà-bà nípinlẹ̀ Èkó. Ótọkasi pé, óléní Continue Reading