Home Posts tagged Mr. Mutiu Agboke
Yoruba

Àjọ INEC Bẹ̀rẹ̀ Àfihàn Àkọsílẹ̀ Orúkọ Olùdìbò Nípinlẹ̀ Ọ̀yọ́

Àjọ elétò ìdìbò ilẹ̀yí, INEC, ẹ̀ka tìpínlẹ̀ ọ̀yọ́ ti bẹ̀rẹ̀ sísàfihàn àkọsílẹ̀ orúkọ àwọn olùdìbò tuntun káàkiri àwọn ìjọba ìbílẹ̀ mẹ́tẹ̀ẹ̀tàlélọ́gbọ̀n tó wà nípinlẹ̀ yí. Àkọsílẹ̀ olùdìbò tuntun yi ló jẹ́ ti àwọn tí wọ́n sẹ̀sẹ̀ forúkọ sílẹ̀ nínú ìpele àkọ́kọ́ ìforúkọ sílẹ̀ olùdìbò tọdún 2021 nípinlẹ̀ ọ̀yọ́. Ọga àgbà àjọ INEC, nípinlẹ̀ yí, Ọ̀gbẹ́ni […]Continue Reading
Politics

LG Election: INEC Hands Over Eighteen Active Political Parties to OYSIEC

Oyo State Independent Electoral Commission, OYSIEC, has given assurance that forthcoming local government election in the state will reflect the choice of the people. Chairman OYSIEC, Are Isiaka Olagunji made the pledge during a courtesy visit to the Office of The Independent National Electoral Commission, INEC in Ibadan. Are Olagunju, who noted that previous local […]Continue Reading
Politics

INEC Holds Forum on Electoral Violence

Violence has remained a symbolic feature of most elections in Nigeria with the last general elections recording tales of unpleasantness in most part of the country. An attempt to forestall this in coming elections informed a Stakeholder’s Election Forum organised by the Independent National Electoral Commission, INEC. At the forum which kicked off with political […]Continue Reading